Orin Dáfídì àti Ìwé Òwe

Orin Dáfídì àti Ìwé Òwe

Ọjọ́ 372

Awon eniyan ti won n sisę ni YouVersion ni won ko iwe Saamu ati Iwe-Owe po si oju kan lati le ran o lowo ki o le ka iwe Saamu ni igba meji ati Iwe Owe ni igba mejila. Ilana kika yi ni a ti pin si kika fun odun kan gbako.

A sèdá ètò yìí látowó YouVersion. Fún àlàyé síwájú sí àti àlùmọ́ọ́nì, jọ̀wọ́ lọ sí: www.youversion.com
Nípa Akéde