Awọn ihinrere
Ọjọ́ 30
Ètò yìí, tí a ṣe àkójọ àti àgbékalẹ̀ rẹẹ̀ nípasẹ̀ àwọn ẹgbẹ́ tí ó wà ní YouVersion.com, yoo ràń ọ́ lọ́wọ́ láti ka ìhìnrere mẹ́rẹ̀rin jálẹ̀ ní ọgbọ̀n ọjọ́. Gba òye nípa ìgbésí ayé ati iṣẹ́ Jésù ní ìgbà kéréje.
A sẹ̀dá ètò yìí látọwọ́ YouVersion. Fún àlàyé síwájú sí àti àlùmọ́ọ́nì, jọ̀wọ́ lọ sí: www.youversion.com
Nípa Akéde