Ìyípadà Ọmọ Onínàkúnàá pẹ̀lú Kyle Idleman
![Ìyípadà Ọmọ Onínàkúnàá pẹ̀lú Kyle Idleman](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F1321%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ọjọ́ 7
A fa ètò yí jáde látinú ìwé Kyle Idleman "AHA," máa fọkàn báalọ bí ó ti ń ṣàwarí àwọn ǹkan mẹ́ta tó lè túbọ̀ mú wa sún mọ́ Ọlọ́run àti láti yí ayé wa padà fún rere. Ṣé o ṣetán fún àkókò pẹ̀lú Ọlọ́run tí yóò yí ohun gbogbo padà?
A fé láti dúpe lowo David C Cook fún ipese ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí, Jọ̀ọ́ bè eyii wò: https://davidccook.org/books/