Ifi 22:2
Ifi 22:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ní àárín ìgboro rẹ̀, àti níhà èkínní kejì odò náà, ni igi ìyè gbé wà, tí o máa ń so onírúurú èso méjìlá, a sì máa so èso rẹ̀ ni oṣooṣù ewé igi náà sí wà fún mímú àwọn orílẹ̀-èdè láradà.
Pín
Kà Ifi 22