O. Daf 96:1-3
O. Daf 96:1-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ kọrin titun si Oluwa: ẹ kọrin si Oluwa gbogbo aiye. Ẹ kọrin si Oluwa, fi ibukún fun orukọ rẹ̀; ẹ ma fi igbala rẹ̀ hàn lati ọjọ de ọjọ. Sọ̀rọ ogo rẹ̀ lãrin awọn keferi, ati iṣẹ iyanu rẹ̀ lãrin gbogbo enia.
Pín
Kà O. Daf 96