Ẹ kọrin tuntun sí OLúWA: Ẹ kọrin sí OLúWA gbogbo ayé. Ẹ kọrin sí OLúWA, yin orúkọ rẹ̀ ẹ sọ ti ìgbàlà rẹ̀ ní ọjọ́ dé ọjọ́ Ẹ sọ ti ògo rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè àti iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrín gbogbo ènìyàn.
Kà Saamu 96
Feti si Saamu 96
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 96:1-3
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò