Tirẹ̀ li okun, on li o si dá a: ọwọ rẹ̀ li o si dá iyangbẹ ilẹ.
Tirẹ̀ ni òkun, nítorí pé òun ni ó dá a; ọwọ́ rẹ̀ ni ó sì fi dá ìyàngbẹ ilẹ̀.
Tirẹ̀ ni Òkun, nítorí òun ni ó dá a àti ọwọ́ rẹ̀ ni ó fi dá ìyàngbẹ ilẹ̀.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò