O. Daf 94:19
O. Daf 94:19 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ninu ọ̀pọlọpọ ibinujẹ mi ninu mi, itunu rẹ li o nmu inu mi dùn.
Pín
Kà O. Daf 94O. Daf 94:19 Yoruba Bible (YCE)
Nígbà tí àìbàlẹ̀ ọkàn mi pọ̀ pupọ, ìwọ ni o tù mí ninu, tí o dá mi lọ́kàn le.
Pín
Kà O. Daf 94