Mo ranti orin mi li oru: emi mba aiya mi sọ̀rọ: ọkàn mi si nṣe awari jọjọ.
Mo ronú jinlẹ̀ lóru, mo ṣe àṣàrò, mo yẹ ọkàn mi wò.
Mo rántí orin mi ní òru. Èmi ń bá àyà mi sọ̀rọ̀, ọkàn mi sì ń ṣe àwárí jọjọ.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò