O. Daf 77:12
O. Daf 77:12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn emi o ma ṣe àṣaro gbogbo iṣẹ rẹ pẹlu, emi o si ma sọ̀rọ iṣẹ rẹ.
Pín
Kà O. Daf 77O. Daf 77:12 Yoruba Bible (YCE)
N óo máa ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ; n óo sì máa ronú lórí àwọn iṣẹ́ ribiribi tí o ṣe.
Pín
Kà O. Daf 77