O. Daf 57:2-3
O. Daf 57:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi o kigbe pe Ọlọrun Ọga-ogo; si Ọlọrun ti o ṣe ohun gbogbo fun mi. On o ranṣẹ lati ọrun wá, yio si gbà mi bi ẹniti nfẹ gbe mi mì tilẹ nkẹgàn mi. Ọlọrun yio rán ãnu rẹ̀ ati otitọ rẹ̀ jade.
Pín
Kà O. Daf 57