ORIN DAFIDI 57:2-3

ORIN DAFIDI 57:2-3 YCE

Mo ké pe Ọlọrun Ọ̀gá Ògo, Ọlọrun tí ó mú èrò rẹ̀ ṣẹ fún mi. Yóo ranṣẹ láti ọ̀run wá, yóo gbà mí là, yóo dójú ti àwọn tí ń lépa ẹ̀mí mi. Ọlọrun yóo fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ ati òtítọ́ rẹ̀ hàn!