Ṣugbọn iwọ, Oluwa, ṣãnu fun mi, ki o si gbé mi dide, ki emi ki o le san a fun wọn.
Ṣugbọn, OLUWA, ṣàánú mi; gbé mi dìde, kí n lè san ẹ̀san fún un.
Ṣùgbọ́n ìwọ OLúWA, ṣàánú fún mi; gbé mi sókè, kí ń ba lè san fún wọn.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò