Nitori, Oluwa, iwọ li emi duro dè, iwọ o gbọ́, Oluwa Ọlọrun mi.
Ṣugbọn, OLUWA, ìwọ ni mò ń dúró dè; OLUWA, Ọlọrun mi, ìwọ ni o óo dá mi lóhùn.
Ṣùgbọ́n sí ọ OLúWA, ìwọ ni mo dúró dè; ìwọ ni, Olúwa Ọlọ́run mi, ẹni tí yóò dáhùn.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò