Ọkàn wa dúró de OLúWA; òun ni ìrànlọ́wọ́ wa àti asà wa.
Ọkàn wa duro de Oluwa: on ni iranlọwọ wa ati asà wa.
Ọkàn wa ní ìrètí lọ́dọ̀ OLUWA; òun ni olùrànlọ́wọ́ ati ààbò wa.
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò