O. Daf 24:1
O. Daf 24:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
TI Oluwa ni ilẹ, ati ẹkún rẹ̀; aiye, ati awọn ti o tẹdo sinu rẹ̀.
Pín
Kà O. Daf 24O. Daf 24:1 Yoruba Bible (YCE)
OLUWA ló ni ilẹ̀ ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀, òun ló ni ayé, ati gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀
Pín
Kà O. Daf 24