Ki iwọ ki ó ma leke, Oluwa, li agbara rẹ; bẹ̃li awa o ma kọrin, ti awa o si ma yìn agbara rẹ.
A gbé ọ ga, nítorí agbára rẹ, OLUWA! A óo máa kọrin, a óo sì máa yin agbára rẹ.
Gbígbéga ni ọ́ OLúWA, nínú agbára rẹ; a ó kọrin, a ó yín agbára a rẹ̀.
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò