O. Daf 16:8
O. Daf 16:8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi ti gbé Oluwa kà iwaju mi nigbagbogbo; nitori o wà li ọwọ ọtún mi, a kì yio ṣi mi ni ipò.
Pín
Kà O. Daf 16O. Daf 16:8 Yoruba Bible (YCE)
Mò ń wo OLUWA ní iwájú mi nígbà gbogbo, nítorí pé Ọlọrun dúró tì mí, ẹsẹ̀ mi kò ní yẹ̀.
Pín
Kà O. Daf 16