Oluwa da gbogbo awọn ti o fẹ ẹ si: ṣugbọn gbogbo enia buburu ni yio parun.
OLUWA dá gbogbo àwọn tí ó fẹ́ ẹ sí, ṣugbọn yóo pa gbogbo àwọn eniyan burúkú run.
OLúWA dá gbogbo àwọn tí ó ní ìfẹ́ sẹ sí ṣùgbọ́n gbogbo àwọn ẹni búburú ní yóò parun.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò