O. Daf 126:5-6
O. Daf 126:5-6 Yoruba Bible (YCE)
Àwọn tí ń fọ́n irúgbìn pẹlu omi lójú, jẹ́ kí wọn kórè rẹ̀ tayọ̀tayọ̀. Ẹni tí ń gbé irúgbìn lọ sí oko tẹkúntẹkún, yóo ru ìtí ọkà pada sílé tayọ̀tayọ̀.
O. Daf 126:5-6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Awọn ti nfi omije fún irugbin yio fi ayọ ka. Ẹniti nfi ẹkun rìn lọ, ti o si gbé irugbin lọwọ, lõtọ, yio fi ayọ̀ pada wá, yio si rù iti rẹ̀.