O ya lati gbẹkẹle Oluwa, jù ati gbẹkẹle enia lọ.
Ó sàn láti sá di OLUWA, ju ati gbẹ́kẹ̀lé eniyan lọ.
Ó dára láti máa gbẹ́kẹ̀lé OLúWA ju àti gbẹ́kẹ̀lé ènìyàn lọ.
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò