O fi ọgbọ́n yà ẹnu rẹ̀; ati li ahọn rẹ̀ li ofin iṣeun.
Ọ̀rọ̀ ọgbọ́n ní ń jáde láti ẹnu rẹ̀, a sì máa kọ́ni ní ẹ̀kọ́ àánú.
A sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ọgbọ́n ìkọ́ni òtítọ́ sì ń bẹ létè e rẹ̀
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò