Owe 31:14
Owe 31:14 Yoruba Bible (YCE)
Obinrin náà dàbí ọkọ̀ ojú omi oníṣòwò, tí ó ń mú oúnjẹ wálé láti ọ̀nà jíjìn réré.
Pín
Kà Owe 31Owe 31:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ó dàbí ọkọ̀ ojú omi tí àwọn oníṣòwò; ó ń gbé oúnjẹ rẹ̀ wá láti ọ̀nà jíjìn
Pín
Kà Owe 31Owe 31:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
O dabi ọkọ̀ oniṣowo: o si mu onjẹ rẹ̀ lati ọ̀na jijin rére wá.
Pín
Kà Owe 31