Owe 27:23-24
Owe 27:23-24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Iwọ ma ṣaniyan ati mọ̀ ìwa agbo-ẹran rẹ, ki iwọ ki o si bojuto awọn ọwọ-ẹran rẹ. Nitoripe ọrọ̀ ki iwà titi lai: ade a ha si ma wà de irandiran?
Pín
Kà Owe 27Iwọ ma ṣaniyan ati mọ̀ ìwa agbo-ẹran rẹ, ki iwọ ki o si bojuto awọn ọwọ-ẹran rẹ. Nitoripe ọrọ̀ ki iwà titi lai: ade a ha si ma wà de irandiran?