AIYA ọba mbẹ lọwọ Oluwa bi odò omi; on a si dari rẹ̀ si ìbikibi ti o wù u.
Orísun omi ni ọkàn ọba lọ́wọ́ OLUWA, ibi tí ó bá wu Oluwa ni ó ń darí rẹ̀ sí.
Ọkàn ọba ń bẹ lọ́wọ́ OLúWA; a máa darí rẹ̀ lọ ibi tí ó fẹ́ bí ipa omi.
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò