Owe 16:21-23
Owe 16:21-23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọlọgbọ́n aiya li a o pè li amoye: didùn-ète a si ma mu ẹkọ́ pọ̀. Oye li orisun ìye fun ẹniti o ni i: ṣugbọn ẹkọ́ aṣiwère ni iwère. Aiya ọlọgbọ́n mu ọ̀rọ ẹnu rẹ̀ gbọ́n, o si mu ẹkọ́ pọ̀ li ète rẹ̀.
Pín
Kà Owe 16Owe 16:21-23 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Owe 16