Ti OLUWA ni òṣùnwọ̀n pípé, iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ni gbogbo ohun tí à ń wọ̀n.
Òdínwọ̀n àti òṣùwọ̀n òtítọ́ wá láti ọ̀dọ̀ OLúWA; gbogbo wíwúwo àpò jẹ́ láti ọwọ́ rẹ̀.
Iwọn ati òṣuwọn otitọ ni ti Oluwa: gbogbo okuta-ìwọn àpo, iṣẹ rẹ̀ ni.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò