Owe 15:24-26
Owe 15:24-26 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọ̀na ìye lọ soke fun ọlọgbọ́n, ki o le kuro ni ipo-okú nisalẹ. Oluwa yio run ile agberaga; ṣugbọn yio fi ìpãlà opó kalẹ. Ìro inu enia buburu, irira ni loju Oluwa; ṣugbọn mimọ́ ni ọ̀rọ didùn niwaju rẹ̀.
Pín
Kà Owe 15