ÌWÉ ÒWE 15:24-26

ÌWÉ ÒWE 15:24-26 YCE

Ọ̀nà ọlọ́gbọ́n lọ tààrà sinu ìyè, kí ó má baà bọ́ sinu isà òkú. OLUWA a máa wó ilé agbéraga, ṣugbọn ó ṣe àmójútó ààlà opó. Ohun ìríra ni èrò ọkàn ẹni ibi lójú OLUWA, ṣugbọn ọrọ̀ àwọn ẹni mímọ́ jẹ́ dídùn inú rẹ̀.