Owe 14:32-33
Owe 14:32-33 Bibeli Mimọ (YBCV)
A pa enia buburu run ninu ìwa-buburu rẹ̀; ṣugbọn olododo ni ireti ninu ikú rẹ̀. Ọgbọ́n fi idi kalẹ li aiya ẹniti o moye; ṣugbọn a fi i hàn laiya awọn aṣiwère.
Pín
Kà Owe 14Owe 14:32-33 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Owe 14