ÌWÉ ÒWE 14:32-33

ÌWÉ ÒWE 14:32-33 YCE

Eniyan burúkú ṣubú nítorí ìwà ibi rẹ̀, ṣugbọn olódodo rí ààbò nípasẹ̀ òtítọ́ inú rẹ̀. Ọgbọ́n kún inú ẹni tí ó mòye, ṣugbọn kò sí ohun tí ó jọ ọgbọ́n lọ́kàn òmùgọ̀.