Owe 14:26-27
Owe 14:26-27 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ni ibẹ̀ru Oluwa ni igbẹkẹle ti o lagbara: yio si jẹ ibi àbo fun awọn ọmọ rẹ̀. Ibẹ̀ru Oluwa li orisun ìye, lati kuro ninu ikẹkùn ikú.
Pín
Kà Owe 14Ni ibẹ̀ru Oluwa ni igbẹkẹle ti o lagbara: yio si jẹ ibi àbo fun awọn ọmọ rẹ̀. Ibẹ̀ru Oluwa li orisun ìye, lati kuro ninu ikẹkùn ikú.