Ninu ìbẹ̀rù OLUWA ni igbẹkẹle tí ó dájú wà, níbẹ̀ ni ààbò wà fún àwọn ọmọ ẹni. Ìbẹ̀rù OLUWA ni orísun ìyè, òun níí mú ká yẹra fún tàkúté ikú.
Kà ÌWÉ ÒWE 14
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ÌWÉ ÒWE 14:26-27
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò