Owe 13:24-25
Owe 13:24-25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹniti o ba fà ọwọ paṣan sẹhin, o korira ọmọ rẹ̀; ṣugbọn ẹniti o fẹ ẹ a ma tète nà a. Olododo jẹ to itẹrun ọkàn rẹ̀; ṣugbọn inu awọn enia buburu ni yio ṣe alaini.
Pín
Kà Owe 13Owe 13:24-25 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Owe 13