Owe 13:12-14
Owe 13:12-14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ireti pipẹ mu ọkàn ṣàisan; ṣugbọn nigbati ifẹ ba de, igi ìye ni. Ẹnikan ti o ba gàn ọ̀rọ na li a o parun: ṣugbọn ẹniti o bẹ̀ru ofin na, li a o san pada fun. Ofin ọlọgbọ́n li orisun ìye, lati kuro ninu okùn ikú.
Pín
Kà Owe 13