Owe 12:19-20
Owe 12:19-20 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ete otitọ li a o mu duro lailai; ṣugbọn ahọn eke, ìgba diẹ ni. Ẹtan wà li aiya awọn ti nrò ibi: ṣugbọn fun awọn ìgbimọ alafia, ayọ̀ ni.
Pín
Kà Owe 12Ete otitọ li a o mu duro lailai; ṣugbọn ahọn eke, ìgba diẹ ni. Ẹtan wà li aiya awọn ti nrò ibi: ṣugbọn fun awọn ìgbimọ alafia, ayọ̀ ni.