Jesu si kigbe soke li ohùn rara, o jọwọ ẹmi rẹ̀ lọwọ. Aṣọ ikele tẹmpili si ya si meji lati oke de isalẹ.
Ṣugbọn Jesu kígbe tòò, ó mí kanlẹ̀ ó bá dákẹ́. Aṣọ ìkélé tí ó wà ninu Tẹmpili bá ya sí meji láti òkè dé ilẹ̀.
Jesu sì tún kígbe sókè ni ohùn rara, ó jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀ lọ́wọ́. Aṣọ ìkélé tẹmpili sì fàya sí méjì láti òkè dé ìsàlẹ̀.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò