Luk 14:23
Luk 14:23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Oluwa na si wi fun ọmọ-ọdọ na pe, Jade lọ si opópo, ati si ọ̀na ọgbà, ki o si rọ̀ wọn lati wọle wá, ki ile mi le kún.
Pín
Kà Luk 14Luk 14:23 Yoruba Bible (YCE)
Oluwa iranṣẹ náà sọ fún un pé, ‘Lọ sí ọ̀nà oko, kí o bẹ àwọn ẹni tí o bá rí, kí wọ́n wọlé wá, kí inú ilé mi baà kún.
Pín
Kà Luk 14Luk 14:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Olúwa náà sì wí fún ọmọ ọ̀dọ̀ náà pé, ‘Jáde lọ sí òpópó, àti sí ọ̀nà ọgbà, kí o sì rọ̀ wọ́n láti wọlé wá, kí ilé mi lè kún.
Pín
Kà Luk 14Luk 14:23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Oluwa na si wi fun ọmọ-ọdọ na pe, Jade lọ si opópo, ati si ọ̀na ọgbà, ki o si rọ̀ wọn lati wọle wá, ki ile mi le kún.
Pín
Kà Luk 14