Luk 14:23

Luk 14:23 YBCV

Oluwa na si wi fun ọmọ-ọdọ na pe, Jade lọ si opópo, ati si ọ̀na ọgbà, ki o si rọ̀ wọn lati wọle wá, ki ile mi le kún.

Àwọn fídíò fún Luk 14:23