Luk 10:41
Luk 10:41 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn Oluwa dá a lóhùn pé, “Mata! Mata! Ò ń ṣe aájò, o sì ń dààmú nípa ohun pupọ.
Pín
Kà Luk 10Luk 10:41 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn Jesu si dahùn, o si wi fun u pe, Marta, Marta, iwọ nṣe aniyan ati lãlã nitori ohun pipọ
Pín
Kà Luk 10