Oluwa, yi wa pada sọdọ rẹ, awa o si yipada; sọ ọjọ wa di ọtun gẹgẹ bi ti igbãni.
Mú wa pada sọ́dọ̀ ara rẹ, OLUWA, kí á lè pada sí ipò wa. Mú àwọn ọjọ́ àtijọ́ wa pada.
Mú wa padà sí ọ̀dọ̀ rẹ, OLúWA, kí àwa kí ó le padà; mú ọjọ́ wa di tuntun bí ìgbàanì
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò