Ẹk. Jer 3:23-24
Ẹk. Jer 3:23-24 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọtun ni li orowurọ; titobi ni otitọ rẹ. Oluwa ni ipin mi, bẹ̃li ọkàn mi wi; nitorina ni emi ṣe reti ninu rẹ̀.
Pín
Kà Ẹk. Jer 3Ẹk. Jer 3:23-24 Yoruba Bible (YCE)
ọ̀tun ni wọ́n láràárọ̀, òtítọ́ rẹ̀ pọ̀. Ọkàn mi wí pé, “OLUWA ni ìpín mi, nítorí náà lọ́dọ̀ rẹ̀ ni ìrètí mi wà.”
Pín
Kà Ẹk. Jer 3