Ẹk. Jer 3:21-23
Ẹk. Jer 3:21-23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Eyi ni emi o rò li ọkàn mi, nitorina emi o ma reti. Ãnu Oluwa ni, ti awa kò parun tan, nitori irọnu-ãnu rẹ kò li opin. Ọtun ni li orowurọ; titobi ni otitọ rẹ.
Pín
Kà Ẹk. Jer 3Ẹk. Jer 3:21-23 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn mo tún ń ranti nǹkankan, mo sì ní ìrètí. Nítorí pé Ìfẹ́ OLUWA tí kì í yẹ̀ kò nípẹ̀kun, àánú rẹ̀ kò sì lópin; ọ̀tun ni wọ́n láràárọ̀, òtítọ́ rẹ̀ pọ̀.
Pín
Kà Ẹk. Jer 3