Joṣ 6:18
Joṣ 6:18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ati ẹnyin, bi o ti wù ki o ri, ẹ pa ara nyin mọ́ kuro ninu ohun ìyasọtọ, ki ẹ má ba yà a sọ̀tọ tán ki ẹ si mú ninu ohun ìyasọtọ na; ẹnyin a si sọ ibudó Israeli di ifibu, ẹnyin a si mu iyọnu bá a.
Pín
Kà Joṣ 6Joṣ 6:18 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Joṣ 6