Isa 52:10
Isa 52:10 Yoruba Bible (YCE)
OLUWA yóo lo agbára mímọ́ rẹ̀, lójú àwọn orílẹ̀-èdè, gbogbo eniyan, títí dé òpin ayé, yóo sì rí ìgbàlà Ọlọrun wa.
Pín
Kà Isa 52Isa 52:10 Bibeli Mimọ (YBCV)
Oluwa ti fi apá mimọ́ rẹ̀ hàn li oju gbogbo awọn orilẹ-ède; gbogbo opin aiye yio si ri igbala Ọlọrun wa.
Pín
Kà Isa 52