Isa 40:3
Isa 40:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ohùn ẹniti nkigbe ni ijù, ẹ tún ọ̀na Oluwa ṣe, ṣe opópo titọ́ ni aginjù fun Ọlọrun wa.
Pín
Kà Isa 40Isa 40:3 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ gbọ́ ohùn akéde kan tí ń wí pé, “Ẹ tún ọ̀nà OLUWA ṣe ninu aginjù, ẹ la òpópónà títọ́ fún Ọlọrun wa ninu aṣálẹ̀.
Pín
Kà Isa 40