Isa 40:29
Isa 40:29 Bibeli Mimọ (YBCV)
O nfi agbara fun alãrẹ̀; o si fi agbara kún awọn ti kò ni ipá.
Pín
Kà Isa 40Isa 40:29 Yoruba Bible (YCE)
A máa fún aláàárẹ̀ ní okun. A sì máa fún ẹni tí kò lágbára ní agbára.
Pín
Kà Isa 40O nfi agbara fun alãrẹ̀; o si fi agbara kún awọn ti kò ni ipá.
A máa fún aláàárẹ̀ ní okun. A sì máa fún ẹni tí kò lágbára ní agbára.