Nitori Oluwa ni onidajọ wa, Oluwa li olofin wa, Oluwa li ọba wa; on o gbà wa là.
Nítorí pé OLUWA ni onídàájọ́ wa, òun ni alákòóso wa; OLUWA ni ọba wa, òun ni yóo gbà wá là.
Nítorí OLúWA ni onídàájọ́ wa, OLúWA ni onídàájọ́ wa, OLúWA òun ni ọba wa; òun ni ẹni tí yóò gbà wá là.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò