Deu 1:12-13
Deu 1:12-13 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi o ti ṣe le nikan rù inira nyin, ati ẹrù nyin, ati ìja nyin? Ẹ mú awọn ọkunrin ọlọgbọ́n wá, ati amoye, ati ẹniti a mọ̀ ninu awọn ẹ̀ya nyin, emi o si fi wọn jẹ olori nyin.
Pín
Kà Deu 1Emi o ti ṣe le nikan rù inira nyin, ati ẹrù nyin, ati ìja nyin? Ẹ mú awọn ọkunrin ọlọgbọ́n wá, ati amoye, ati ẹniti a mọ̀ ninu awọn ẹ̀ya nyin, emi o si fi wọn jẹ olori nyin.