I. Pet 3:12-13
I. Pet 3:12-13 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori oju Oluwa mbẹ lara awọn olododo, etí rẹ̀ si ṣí si ẹbẹ wọn: ṣugbọn oju Oluwa nwo awọn ti nṣe buburu. Tani yio si ṣe nyin ni ibi, bi ẹnyin ba jẹ onítara si ohun rere?
Pín
Kà I. Pet 3I. Pet 3:12-13 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí Oluwa ń ṣọ́ àwọn olódodo, ó sì dẹ etí sí ẹ̀bẹ̀ wọn. Ṣugbọn ojú Oluwa kan sí àwọn tí ó ń ṣe burúkú.” Ta ni lè ṣe yín ní ibi tí ẹ bá ní ìtara fún ohun tíí ṣe rere?
Pín
Kà I. Pet 3